Paul Emmanuel – Agbara (Mp3 Download, Lyrics) » Newslodge
Paul Emmanuel – Agbara (Mp3 Download, Lyrics
Video: Agbara by Paul Emmanuel
Agbara Lyrics by Paul Emmanuel
Agbara t’oju agbara lo o
Ni ti Jeeesu mi o
Agbara t’ju agbara lo ooo Iye
Ye eh eh eh
All power belongs to You
When l come l come in the Spirit
When l speak l speak in the Spirit
When l pray l pray in the Holy Ghost
And when l dance l dance in the Spirit
When l burn l burn in the Spirit
When l burn l burn principalities
When l burn l burn down infirmities
So l roar l roar in the Spirit
Agbara t′oju agbara lo o
Ni ti Jesu mi o
Agbara t’ju agbara lo ooo
Niti Jeesu mi
Agbara t’oju agbara lo o
Ni ti Jesu mi o
Agbara t′ju agbara lo ooo
Niti Jeesu mi
Agbara t′onji oku dide
Ma niti Jeeesu mi oh
Nigbati moro ise iyanu re
Mo f’ori bale fun o
O f′aye mi dabira oh
O f’aye mi se iyanu
Baba nse bebe l′aye mi o
Oluranti mi modupe
Kini mafi san fun oh o
Oju ina eleti ajere
Ayeraye modupe
Ayeraye mo yin o l’ogo
Ayeraye modupe oh
O f′aye mi lu satani mole o
Agbara t’oju agbara lo o
Niti Jeeesu mi oh
Agbara itun sile oh
Niti Jeeesu mi oh
Agbara t’on so′ agan di olomo
Ni ti Jeeesu mi oh
Alaso′ fun fun emi awon woli
Ni ti Jeeesu mi oh
Agbara t’oju agbara lo oh
Agbara to′ji oku dide